• Logo
  • Register LPV FORUM
    Stats: 10,831 members, 22,283 posts.
    Date: September 22, 2019, 05:5 AM

 Ìwà rere

DP
By rebecca1 • June 24, 2019, 06 AM • 443 views • 124 comments

Kíló yẹ ká dìmú

Ìwà rere

Kíló yẹ ká tọ́jú

Ìwà rere


Ìwà rere lẹ̀sọ́

Ìwà rere laṣọ

Ìwà rereIbo là bá tẹ̀ sí

Ọ̀nà rere

Ibo là bá rìn sí


Ọ̀nà rere

Ọ̀nà rere kì ń dáni

Ọ̀na rere kì ń sún ni

Èyí yóò jẹ́ ipa mi


Ọ̀nà rere

Share 

   Related Post viewed by other

124 Replies | Last update July 24, 2019, 07 AM | Last comment